World Cup 2018: Denmark na Peru pẹ̀lú àmì ayò 1-0

Peru
Àkọlé àwòrán, Ikọ Peru gbiyanju lọpọlọpo ninu ifesewonse naa, amo Denmark lo jawe olubori nigbati Yussuf Poulsen sọ bọọlu sinu awọn.
Published

Ikọ orilẹede Denmark bẹrẹ ifẹsẹwọnsẹ alakọkọ pẹlu ikọ Peru ninu idije Ife Ẹyẹ Agbaye ti Russia 2018 pẹlu ami ayo eyokan si odo.

Ikọ Peru sọ bọọlu kọjú-sími-gbáa-sílé nu, pẹlu ọpọlọpọ anfaani lati gba bọọlu wọ inu awọn.

Peru gbiyanju lọpọlọpọ ninu ifẹsẹwọnsẹ naa, amọ Denmark lo jawe olubori nigbati Yussuf Poulsen sọ bọọlu sinu awọn ni isẹju mọkandinlọgọta ti ifẹsẹwọnsẹ naa bẹrẹ.

Amin iyasọtọ kan
Àkọlé fídíò, Russia 2018: Nàìjíríà dúró gìdìgbà, ki Ọlọrun fún wa ṣe

France ni ikọ Peru yoo ma a koju, nigbati Denmark yoo ma fẹsẹwọnsẹ pẹlu Australia lẹyin ti wọn ti gba ami ayo mẹta lori atẹ isori kẹta ti Ife Ẹyẹ Agbaye Russia 2018.

Amin iyasọtọ kan

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, Gbolahan Kabiawu: Fífi ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ dára fún ẹ̀yà ara