Ọ̀lọ́pàà ìlú ọba ti fi páńpẹ́ ọba mú olùdásílẹ̀ Wikileaks, Julian Assange ní ìlú London.

Àkọlé fídíò, Ọ̀lọ́pàà ìlú ọba ti fi páńpẹ́ ọba mú olùdásílẹ̀ Wikileaks, Julian Assange ní ìlú London.
Published

Ọlọpaa ilu ọba ti fi panpẹ ọba mu oludasilẹ ẹrọ iroyin Wikileaks, Julian Assange ni ilu London.

Ọwọ ọlọpaa tẹ ẹ lẹyin ti Assange sa asala lọ si ile isẹ asoju ilẹ Ecuado ni ọdun 2012 lati yẹra fun igbesẹ ilẹ Sweden to ti fẹ jẹjọ iwa ẹsun ifipabanilopọ.

Bakan naa ni ilẹ Amẹrika fẹsun kan an wi pe o fi awọn iroyin ijọba ilẹ Amerika to wa ni idakọnkọ si ita.