Wo bí o ṣe leè ṣe ìjìnàsíraẹni ní ibiṣẹ́ lásìkò Coronavirus yìí

Àkọlé fídíò, Wo bí o ṣe leè ṣe ìjìnàsíraẹni ní ibiṣẹ́ lásìkò Coronavirus yìí
Published

Ootọ ni pe o lee fẹ ṣoro diẹ lati ṣe ijinasiraẹni ni ibiṣe lasiko Coronavirus yii.

Ṣugbọn imọran lati ọdọ ajọ to n risi idena ajakalẹ arun ni Naijiria, NCDC, ati WHO ti fidi rẹ mulẹ pe ijinasiraẹni jẹ ọna kan gboogi lara ọna ati dẹkun itankalẹ arun naa.

Nitori naa, ijinasiraẹni ṣe pataki lasiko yii, papa julọ nibi iṣẹ oojọ ẹni.

Ẹ wo fidio yi fun ọna ti ẹ le gba lati ṣe ijinasiraẹni nibi iṣẹ.