O ba ni, ko bajẹ; Idibo yẹ ọjọ igbeyawo wọn amọ wọn dọgbọn si
Pẹlu aworan awọn ibeji ti sisun ti wọn sun idibo siwaju ṣe akoba fun ọjọ igbeyawo wọn ni a n dagbere fun yin.
Ọjọ kẹtalelogun oṣu Keji lo yẹ ki igbeyawo naa waye, ṣugbọn wọn sun un sẹyin si ọjọ kejilelogun.
Ẹ le wo ifọrọwanilẹwo pẹlu wọn ni
Owurọ ọjọ Abamẹta ni ki ẹ darapọ mọ wa fun ẹkunrẹrẹ iroyin lori eto idibo gbogboogbo kaakiri Naijiria.
























